[go: up one dir, main page]

Jump to content

Roald Amundsen

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Roald Engelbregt Gravning Amundsen
Roald Engelbregt Gravning Amundsen
Ọjọ́ìbí(1872-07-16)16 Oṣù Keje 1872
Borge, Østfold, Norway
Aláìsíc. 18 June 1928(1928-06-18) (ọmọ ọdún 55)
unknown
Iṣẹ́Explorer
Parent(s)Jens Amundsen, Hanna Sahlqvist

Roald Engelbregt Gravning Amundsen (Àdàkọ:IPA-sv; 16 July 1872 – c. 18 June 1928) je oniwakiri ara Norway. ọmọ ọdún márùn dín ní ọgọ́ta ni. Ẹni àkọ́kọ́ tí ó dé póólù gúsù. Ó ṣe alábápàdá ikú rẹ̀ ní ibi ìjàmbá ọkọ̀ òfurufú ní odò bárẹ́ǹtì. Àwon òbí rẹ ni Jen Amundsen àti Hanna Sahlqvist. Ó gba àmì ẹ̀yẹ Úbádì ní ọdún 1907 láti ọwọ àwọn Ẹgbẹ arin ìrìn àjò aláwárí fún eni àkókó tí ó ṣe àwárí agbègbè Àríwá ìlà oòrùn. Kò gbè ìyàwó, bẹ́ẹ́ní kò sì bí omo.