iwe-idahun ibeere-idanwo
Appearance
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]From ìwé-ìdáhùn (“answer sheet”) + ìbéèrè-ìdánwò (“test questions”), from ìwé (“paper, book”) + ìdáhùn (“answer”) + ìbéèrè (“question”) + ìdánwò (“test”)
Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ìwé-ìdáhùn ìbéèrè-ìdánwò
- examination paper
- Kí ni àwọ̀ ìwé-ìdáhùn ìbéèrè-ìdánwò ọdún yìí? ― What's the colour of the examination paper this year?