[go: up one dir, main page]

Rita Moreno ni a bini ọjọ kọkanla óṣu december ni ọdun 1931 ti ósijẹ ónijó, akọrin ati óṣere. Rita gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Rita Moreno
Rita Moreno
Ọjọ́ìbíRosa Dolores Alverío Marcano
11 Oṣù Kejìlá 1931 (1931-12-11) (ọmọ ọdún 92)
Humacao, Puerto Rico
Iṣẹ́
  • Actress
  • singer
  • dancer
Ìgbà iṣẹ́1943–present
WorksRita Moreno on screen and stage
Olólùfẹ́
Leonard Gordon
(m. 1965; died 2010)
Àwọn ọmọ1
AwardsList of awards and nominations received by Rita Moreno


Igbesi Aye Arabinrin naa

àtúnṣe

Àbi Rita si Humacao, Puerto Rico fun Rosa Maria (Ólúran àṣọ lobinrin) ati Francisco José (Agbẹ)[2]. Órùkọ àpèjẹ óṣèrè lobinrin naa ni Rosita. Moreno bẹrẹ si ni kọ ijó akọkọ lati ọwọ ónijó ilẹ spanish ti órukọ rẹ njẹ Paco Cansino. Óṣere lobinrin naa kó ipa rẹ Broadway akọkọ gẹgẹbi Angelina ninu Skydrift nigba ti o wa ni ọmọ ọdun mẹtala. Irin àjó Moreno lori èrè agbèlèwo bẹrẹ ni ọdun to pada pẹ ti Golden Age ti Hollywood[3].

Lati ọdun 1954 titi dè ọdun 1962, Moreno wa ni ipàṣèpọ ti ó ṣẹ bẹ dọmọran pẹlu Marlon Brandon nibi ti o ti lóyun fun ṣugbọn ọmọ naa pada ku sinu óyun nigba ti ó fẹ yọ danu[4]. Ni ọdun 1965, Móreno fẹ dọkita óluwó ọkan Leonard Gordon ti o si di manager fun óṣere lobinrin naa lẹyin ti o fẹyinti ni idi iṣẹ iṣègun[5][6]. Ni ọdun 1995, ọkọ ati iyawó naa kó lọ si Berkeley ni California nibi ti wọn si ti wa papọ titi Leonard fi ku ni ọdun 2010. Moreno ati Gordon bi ọmọ obinrin kan Fernanda Gordon Fisher ti o sibi ọmọ meji lọkunrin[7].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

àtúnṣe

Moreno gba ami ẹyẹ ti Emmy, Grammy, Oscar ati Tony[8][9][10]. óṣere lobinrin naa jẹ ọkan lara awọn mẹrin lèèlogun ti wọn fi jẹ Triple Crown of Acting. Ni ọdun 2004, Rita gba medal óminira ti arẹ órilẹ ede lati ọdọ George W.Bush ti ilẹ amẹrica.

Ni ọdun 2009, Àrẹ Barack Obama fun óṣere naa ni Medal Arts ti national.Ni ọdun 2015, óṣere lobinrin naa gba ami ẹyẹ ti kennedy center honor fun ipa rẹ ninu gbigbe àṣà ilẹ amẹrica larugẹ pẹlù èrè óritage[11]. Ni ọdun 2019, Rita gba Àmi ẹyẹ ti peabody[12].

Itọkasi

àtúnṣe