Victor Omololu Olunloyo
Ìrísí
Victor Omololu Olunloyo | |
---|---|
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo | |
In office October 1983 – December 1983 | |
Asíwájú | Bola Ige |
Arọ́pò | Oladayo Popoola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹrin 1935 |
Àwọn ọmọ | Kemi Omololu-Olunloyo (ọmọ obìnrin) |
Victor Omololu Olunloyo (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin ọdún 1935) jẹ́ onímọ̀ Mati tí ó di Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, Nàìjíríà ní oṣù Kẹ̀wá ọdún 1983, ó di ipò náà mú fún ìgbà díẹ̀ kí ìjọba ológun Muhammadu Buhari tó gba ìjọba ní oṣù Kejìlá ọdún 1983. Ó padà darapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú People's Democratic Party (PDP) ní Ìpínlẹ̀ Oyo.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]