Tunbosun Aiyedehin
Ìrísí
Tunbosun Aiyedehin (tí a bí ní ọjọ́ ogún, oṣù kẹfà ọdún 1969) tí ó gbajúmò gẹ́gẹ́ bí Tuby jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa Two Brides and a Baby àti Kpians: The Feast of Soul
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó kópa nínú eré bíi Hakkunde, Troubled Waters, Moth to a Flame, Hell or High Water, Lockdown, Dear Bayo, Mrs. & Mrs. Johnson and The Ten Virgins lẹ́yìn ìgbà tí ó darapọ̀ mọ́ Nollywood. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tí ó dára jù lọ nínú eré dírámà láti ọ̀dọ̀ African Magic ní ọdún 2016. Ó gba àmì ẹ̀yẹ Best of Nollywood Awards ni ọdún 2019 gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin tí ó dára jù lọ.
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Two Brides and a Baby (2011)
- Kpians: The Feast of Souls (2014)
- A Day with Death (2014)
- Mrs. & Mrs. Johnson (2015)
- Before 30 (2015)
- Schemers (2015)
- Moth to a Flame (2016)
- 93 Days (2016)
- Hell or High Water (2016)
- Oreva (2017)
- Hakkunde (2017)
- Troubled Waters (2017)
- E.V.E - Audi Alteram Partem (2018)
- The Ten Virgins (2019)
- Black Monday (2019)
- Clustered Colours (2019)
- Lockdown (2019)
- Stones (2019)
- The Sessions (2019)
- Dear Bayo (2020)
- It's a Crazy World (2020)
- Mirabel (2020)
- Yahoo Taboo (2020)
- Country Head (2020)