[go: up one dir, main page]

Jump to content

Ebenezer Obey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ebenezer Obey

Ebenezer Obey jẹ́ gbajúgbajà olórin jùjú láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kẹ́ta oṣù kẹrin ọdún 1942. Àpèjá orúkọ rẹ̀ ni Ebenezer Rẹ̀mílẹ́kún Àrẹ̀mú Ọláṣùpọ̀ Obey-Fabiyi. Ìlú Idogo, ní ẹnu ibodè tí ó pa ààlà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Benin ni a ti bi Ebenezer Obey. Orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ni "Chief Commander".