[go: up one dir, main page]

Jump to content

Doctor Bello

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Doctor Bello
AdaríTony Abulu
Olùgbékalẹ̀Tony Abulu
Òǹkọ̀wéTony Abulu
Àwọn òṣèré
Ìyàwòrán sinimáScott St. John
Ilé-iṣẹ́ fíìmùBlack Ivory Communications
OlùpínAMC Theatres
Déètì àgbéjáde
  • 22 Oṣù Kejì 2013 (2013-02-22) (U.S.)
Àkókò95 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
United States
ÈdèEnglish
Yoruba

Doctor Bello jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2013, èyí tí Tony Abulu darí, tí àwọn ọ̀ṣèré bíi Isaiah Washington, Vivica A. Fox, Jimmy Jean-Louis, Genevieve Nnaji, Stephanie Okereke, Justus Esiri, Ebbe Bassey àti Jon Freda kópa nínú rẹ̀.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Official website of Doctor Bello Movie". Retrieved 9 February 2014.