Arsenal F. C.
Full name | Arsenal Football Club | |||
---|---|---|---|---|
Nickname(s) | The Gunners | |||
Founded | Oṣù Kẹ̀wá 1886[1] | as Dial Square|||
Ground | Emirates Stadium (Capacity: 60,704[2]) | |||
Owner | Kroenke Sports & Entertainment | |||
Chairman | Sir Chips Keswick | |||
Head coach | Mikel Arteta | |||
League | Àdàkọ:English football updater | |||
Àdàkọ:English football updater | Àdàkọ:English football updater | |||
Website | Club home page | |||
| ||||
Current season |
Arsenal Football Club jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ṣiṣẹ́ tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú Islington ni London lorílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, tí ó ń díje nínú Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìdíje Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí ó ga jùlọ lorílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí tí gba ìfẹ́-ẹ̀yẹ mẹ́tàlá nínú Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, bẹ́ẹ̀ náà ni ó gba ife ẹ̀yẹ FA Cup mẹ́tàlá àti àwọn àṣeyọrí mìíràn nínú ìdíje Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá. Arsenal F. C. jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá àkọ́kọ́ láti apá gúúsù orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì láti darapọ̀ mọ́ Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì lọ́dún 1893, [3] wọn sìn tún jẹ́ ipò kejì nínú àwọn ikọ̀ tó pegedé jùlọ nínú àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá jẹun lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì.[4] Lọ́dún 1930 àti jù bẹ́ẹ̀ lọ, Arsenal F. C. gba ife ẹ̀yẹ márùn-ún, àti àwọn ife ẹ̀yẹ mìíràn tó tó márùn-ún. Lẹ́yìn náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ife ẹ̀yẹ, pàápàá jù lọ Ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "10/05/2017 -'Royal Arsenal' formed in Woolwich". www.arsenal.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 November 2018.
- ↑ "Premier League Handbook 2019–20" (PDF). Premier League. p. 6. Retrieved 4 September 2019.
- ↑ Ross, James; Heneghan, Michael; Orford, Stuart; Culliton, Eoin (23 June 2016). "English Clubs Divisional Movements 1888–2016". Rec.Sport.Soccer Statistics Foundation. Archived from the original on 5 August 2016. Retrieved 5 August 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Pietarinen, Heikki (24 August 2017). "England – First Level All-Time Tables". Rec.Sport.Soccer Statistics Foundation. Archived from the original on 24 August 2017. Retrieved 24 August 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Hodgson, Guy. "Football: How consistency and caution made Arsenal England's greatest". The Independent (London). Archived from the original on 3 March 2016. https://web.archive.org/web/20160303192410/http://www.independent.co.uk/sport/football-how-consistency-and-caution-made-arsenal-englands-greatest-team-of-the-20th-century-1133020.html. Retrieved 13 May 2016.