[go: up one dir, main page]

Jump to content

Charles Rotimi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Charles Rotimi
Rotimi interviewed by the NHGRI Oral History Collection in 2017
ÌbíCharles Nohuoma Rotimi
1957 (ọmọ ọdún 66–67)
Benin City
Ilé-ẹ̀kọ́Howard University
Loma Linda University
Loyola University Chicago
NIH
Ibi ẹ̀kọ́University of Benin (BS)
University of Mississippi (MS)
University of Alabama at Birmingham (MPH)
University of Alabama at Birmingham (PhD)
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síElected to the National Academy of Medicine (2018)

Charles Nohuoma Rotimi (tí wọ́n bí ní ọdún 1957) jẹ́ olùdarí àgbà ní National Institutes of Health (NIH) Ó ṣe ìdásílẹ̀ African Society of Human Genetics ní ọdún 2003. Rotimi kó ipa ribiribi nínú ìṣẹ̀dá Human Heredity and Health in Africa (H3Africa) pẹ̀lú ìrànwọ́ NIH àti Wellcome Trust. Wọ́n yàn án sínú ẹgbẹ́ National Academy of Medicine ní ọdún 2018.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Morris, Kelly (2010-10-23). "Charles Rotimi: engaging Africa in human genomic research" (in English). The Lancet 376 (9750): 1383. doi:10.1016/S0140-6736(10)61943-5. ISSN 0140-6736. PMID 20971351. 
  2. "Charles N. Rotimi, Ph.D.". genome.gov. NHGRI. Retrieved 2019-05-08.