Chanda Rubin
Ìrísí
Chanda Rubin playing in the U.S. Open Champions Team Tennis September 9, 2010 | |
Orílẹ̀-èdè | United States |
---|---|
Ibùgbé | Lafayette, Louisiana, US |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kejì 1976 Lafayette, Louisiana, U.S. |
Ìga | 1.68 m (5 ft 6 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | August 1991 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | US$4,469,990 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 399–254 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 7 WTA, 2 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 6 (April 8, 1996) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | SF (1996) |
Open Fránsì | QF (1995, 2000, 2003) |
Wimbledon | 4R (2002) |
Open Amẹ́ríkà | 4R (1992, 1995, 2002) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 226–160 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 10 WTA, 3 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 9 (April 15, 1996) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | W (1996) |
Open Fránsì | SF (2003) |
Wimbledon | SF (2002) |
Open Amẹ́ríkà | F (1999) |
Last updated on: December 11, 2009. |
Chanda Rubin (ojoibi February 18, 1976) je agba tenis ara Amerika to ti feyinti. O gba ife-eye awon idije WTA Tour enikan meje, ipo re to gajulo ni World No. 6 ni April 8, 1996, leyin igba to de ilajidopin ni Open Australia 1996. Bakanna Rubin de ipo World No. 9 ninu idije enimeji, o gba Open Australia 1996 pelu Arantxa Sánchez Vicario.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |