[go: up one dir, main page]

Jump to content

Coretta Scott King

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Coretta Scott King
King at the 30th anniversary of the March on Washington, 1993
Ọjọ́ìbíCoretta Scott
(1927-04-27)Oṣù Kẹrin 27, 1927
Marion, Alabama, U.S.
AláìsíJanuary 30, 2006(2006-01-30) (ọmọ ọdún 78)
Rosarito Beach, Mexico
Resting placeKing Center for Nonviolent Social Change
(Atlanta, Georgia)
Ẹ̀kọ́Antioch College (BA)
New England Conservatory of Music (BM)
Iṣẹ́Civil rights, women's rights, gay rights, human rights, and equal rights activist; author
Olólùfẹ́
Martin Luther King Jr.
(m. 1953; died 1968)
Àwọn ọmọYolanda King
Martin Luther King III
Dexter Scott King
Bernice King
Àwọn olùbátanYolanda Renee King (granddaughter)
Alveda King (niece)
AwardsGandhi Peace Prize
Coretta Scott King Award for Authors

Coretta Scott King (April 27, 1927 – January 30, 2006) jẹ́ olùkọ̀wé, alákitiyan, aṣíwájú fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà, àtí ìyàwó Martin Luther King Jr.. Ó ṣakitiyan fún ìbáradọ́gba àwọn ọmọ African-American, ó ṣe aṣíwájú fún Civil Rights Movement ní 1960s. King tún jẹ́ akọrin tó lo orin nínú iṣẹ́ rẹ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú. King bá ọkọ rẹ̀ pàdé nkgbà tí wọ́n jọ wà ní ilé-ẹ̀kọ́ yunifásítì ní Boston.