[go: up one dir, main page]

Jump to content

Èdè Ìdomà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìdomà
Sísọ níÌpínlẹ̀ Bẹ́núé, Àrin Nigeria
Ọjọ́ ìdásílẹ̀1991
Ẹ̀yàÌdomà
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀600,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3idu

Ìdomà jẹ́ ẹ̀yà kan lára àwọn ẹ̀yà ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n ń sọ èdè ÌdomàBẹ́núé ìpínlẹ̀ yi ni ó wà ní à́árín gbùngbùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́rin ènìyàn. Àwọn aládùgbóò tàbí tí wọ́n jọ sún mọ́ ara wọn ni: Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Idoma ni wọ́n yan iṣẹ́ àgbẹ̀ láàyò.[1] [2] Wọ́n si máa ń ṣe àpọ́nlé àwọn bàbá ńlá wọn tí wọ́n ti kú.

Àwọn Ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "About Idoma People". Idoma Land. 2008. 
  2. Godwin, Ameh Comrade. "David Mark using University to fool Idoma people – Benue APC". D.