[go: up one dir, main page]

Jump to content

Joy Ogwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joy Ogwu
Permanent Representative of Nigeria to the United Nations
In office
7 May 2008 – May 2017
Arọ́pòTijjani Muhammad-Bande
Foreign Minister of Nigeria
In office
30 August 2006 – 29 May 2007
ÀàrẹOlusegun Obasanjo
AsíwájúNgozi Okonjo-Iweala
Arọ́pòOjo Maduekwe
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Joy Uche Angela Ogwu

22 Oṣù Kẹjọ 1946 (1946-08-22) (ọmọ ọdún 78)
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríà Nàìjíríà
Alma materRutgers University
University of Lagos

Joy Uche Angela Ogwu (tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1946) jẹ́ mínísítà Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí àti asojú Nàìjíríà sí ẹgbẹ́ United Nations ní New York láàrin ọdún 2008 sí 2017.[1][2] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti jẹ́ asojú sí egbẹ́ United Nations làti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[3] Kí ó tó di mínísítà, Ogwu, tí ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, jẹ́ adarí àgbà Nigerian Institute of International Affairs (NIIA).[4]


Ààrẹ Olusegun Obasanjo yàn gẹ́gẹ́ bi òkè òkun ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2006.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Home" (in en-US). Permanent Mission of Nigeria to the United Nations, New York. http://www.nigeriaunmission.org/. 
  2. "New Permanent Representative of Nigeria Presents Credentials" (in en-US). https://www.un.org/press/en/2017/bio4963.doc.htm. 
  3. "Joy Ogwu | Ambassador Series Lecture". events.adelphi.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-25. 
  4. III, Editorial (2019-04-27). "Joy Ogwu, Bolaji Akinyemi: Where are they now?" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-25. 
  5. "Joy Ogwu: Quintessential Diplomat". The Pointer News Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-07-19. Retrieved 2020-05-25.