[go: up one dir, main page]

Jump to content

Diphallia

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Diphallia
DiphalliaDiphallia
DiphalliaDiphallia
Diphallia
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta

Diphallia, penile duplication (PD), diphallic terata, tabi diphallasparatus, jẹ́ ohun àìbójúmu tí kò wọ́pọ̀, leyí tí ọmọ ìkókó maa ní okó méjì. Àkọsílẹ̀ àkọ́kọ́ tí a kọ́kọ́ rí ni tí  Johannes Jacob Wecker ní ọdún  1609.[1][2] Ìru nkan báyìí maa ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ní bíi 5.5 million àwọn ọkùnrin ní  United States.[3]

Àwọn àrùn to ní ṣe pẹ̀lú  renal, vertebral, hindgut, anorectal tàbí àwọn àrùn abínibí míràn ni ó maa ń rọ̀ mọ́ diphallia. O tún ṣeéṣe kí ènìyàn ní àrùn spina bifida.[2] Àtikú ọmọ tí wọ́n bá bí pẹ̀lú PD àti àwọn àrùn tó rọ̀ mọ́ọ yára púpọ̀ látàrí oríṣiríṣi àrùn tí o maa wọlé sí irú ọmọ bẹ́ẹ̀ lára tí ó sì níí ṣe pẹ̀lú renal tàbí àwọn colorectal system irú ọmọ bẹ́ẹ̀.

A ní ìgbàgbọ́ wípé diphallia maa ń wáyé láti inú oyún láàrín ọjọ́ kẹtàlélógún sí ọjọ́ karùnlélógún.

  • A scientific paper of triphallia (3 penises) in a marine snail was reported.[4]
  • An unusual case of a diphallic man with two fully functional penises has been reported in the media.[5][6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Concealed diphallus :a Case report and review of the literature". Journal of Indian Association of Pediatric Surgeons 5 (1): 18–21. 2000. Archived from the original on 2016-03-03. https://web.archive.org/web/20160303192733/http://www.jiaps.com/article.asp?issn=0971-9261;year=2000;volume=5;issue=1;spage=18;epage=21;aulast=Sharma;type=0. Retrieved 2016-08-08. 
  2. 2.0 2.1 Mirshemirani, AR; Sadeghyian, N; Mohajerzadeh, L; Molayee, H; Ghaffari, P (2010). "Diphallus: Report on six cases and review of the literature". Iranian journal of pediatrics 20 (3): 353–7. PMC 3446048. PMID 23056729. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3446048. 
  3. "Indian man wants op to remove extra organ". Reuters. 19 August 2006. Archived from the original on 22 January 2007. Retrieved 2006-08-18. 
  4. Castillo, Viviana M; Brown, Donald I (2012). "One Case of Triphallia in the Marine Snail Echinolittorina peruviana (Caenogastropoda: Littorinidae)". International Journal of Morphology 30 (3): 791. doi:10.4067/S0717-95022012000300003. 
  5. Daniel Rosney (6 January 2015)
  6. Kory Grow (31 December 2014).

Àwọn ìjápò látìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]